Ẹ?? ????? Ọ?ọ?ọ
Islamic Heritage Herbal Clinic jẹ ile iwosan ibile ni ilana Islam. Ibi ti agbekalẹ si lati se iwadi okunfa ati itọju gbogbo ailera ti o jẹ mọ idamu ọkan tabi eyi ti alepe ni aisan ọpọlọ. Iwe pẹlẹbẹ yi wa fun lati jẹ ki e ni imọ ati oye nipa iru awọn eniyan ti an tọju ni ẹka yi ni ile iṣẹ wa.
Awọn Ọrọ Tabi Gbolohun ti o ntọka si awọn eniyan tabi aisan yi ni yii:
Alaisan Ọkan
Alaisan Ọpọlọ
Alaisan Ọpọlọ Ọlọjọ Pipẹ
Were
Ọdẹ Ori
Asinwin
Alaisan Ọpọlọ nipa ogun oloro
Alaisan Ọpọlọ nipa awọn ẹmi airi (Ajunannu).
Awọn apẹrẹ ati ihuwasi ti o saba mọn wọpọ laarin awọn ti a ma n tọju ni ẹka yi nii:
Ihuwasi odi
Dida sọrọ
Ini fẹ si dida wa
Aya jija
Gbigbagbo wipe awọn eniyan miran mọn nipa ero okan wọn
Gbigbagbọ wipe awọn eniyan tabi awọn ẹda kan ngbiyanju lati pa wọn lara
Gbigbọ ọrọ lati inu eti wọn abi inu ori won
Iyan jija laini idi pataki
Iwa jagidijagan
Riri tabi gbigbọ ohun ti ẹlomiran ko gbọ
Gbigbero lati gba ẹmi ara eni
Airorun sun
Ririn kiri oju popo
Inifẹ si idọti ati ọbun
Aibikita nipa itọju ara ẹni
Nini awọn igbagbọ odi
Igberaga ati ijọ ara ẹni loju
Sisun si ita tabi abẹ afara
E wa fun itọju aisan wọn yii pẹlu itọju to daju ni ilana Islam.
Call/WhatsApp: +2348068048800, +2348056234015